Oladips – Twenty Tiri K Lyrics
[INTRO]
Omo iya aje
AYK Beats
Won fe mo e’ye ti mo ni
Won fe eye ti mo naku
23 uncountable
[CHORUS]
Elo OG (elo)
Elo lan ta ile (lan ta ile)
Owo kan wa ni account mi se
Mo fe si s’aiye (mo fe fi s’aiye)
Elo OG (elo)
Elo lan ta Benz (lan ta Benz)
Ile ti mo ra timo ti sanwo
Mo fe kalo fence
Twenty tiri k
Twenty tiri k
Mo mo curency tan je but mo ni twenty tiri k
Twenty tiri k
Twenty tiri k
Mi o mo currency tan je but moni twenty tiri k
[VERSE 1]
Elo le ni te fe fi pe paso
Ah
Te fe fi pe osupa
Owo te ni ti ko ba wo wazo
Elo fi se osuka
Olowo yin ti lo fowo ra ku
Ah
O fowo ra tajutaju
Eni ma ba pade eni ma ku
Sheri igboranso to fi Adelabu
Awa la ni igboro
Awa la ni street
Emi mo lorin
Emi mi mo ni beat
Emi mo lowo
Eyin le ni bank
Awa la wa leyin yin te fi pass
Mo ni mansion kan ti mo fe ra
Mo ni motor kan ti mo fe ra
Oluwa dakun shanumi ah
Mogbe phone mo pe paadi mi
[CHORUS]
Elo OG (elo)
Elo lan ta ile (lan ta ile)
Owo kan wa ni account mi se
Mo fe si s’aiye (mo fe fi s’aiye)
Elo OG (elo)
Elo lan ta Benz (lan ta Benz)
Ile ti mo ra timo ti sanwo
Mo fe kalo fence
Twenty tiri k
Twenty tiri k
Mo mo currency tan je but mo ni twenty tiri k
Twenty tiri k
Twenty tiri k
Mi o mo currency tan je but mo ni twenty tiri k
Ah
[VERSE 2]
Ah
Elo le ni tefe fi pe wizzy
Te fe fi pe David
Igbati to ma muyin la ti eyin
E ma bere wi pe bawo mo se de bi
30GB o n se thirty thousand thirty thousand
O fe pe Wizkid pelu thirty thousand
Tenant lo se yahoo
Nigba ti EFCC de, naso dey carry landlord
Ah oso si mi lenu o bu yosi
Ma woju Uche, pe Obinna si
Nobody fit touch us, ah
We dey okay at last Osinachi
Mo ri mansion kan ti mo fera
Mo ri motor kan ti mo fera
Oluwa dakun shanumi
Mo gbe phone mo pe paadi mi
[Chorus]
Elo OG (elo)
Elo lan ta ile (lan ta ile)
Owo kan wa ni account mi se
Mo fe si s’aiye (mo fe fi s’aiye)
Elo OG (elo)
Elo lan ta Benz (lan ta Benz)
Ile ti mo ra timo ti sanwo
Mo fe kalo fence
Twenty tiri k
Twenty tiri k
Mo mo currency tan je but mo ni twenty tiri k
Twenty tiri k
Twenty tiri k
Mi o mo currency tan je but mo ni twenty tiri k
Ah
[OUTRO]
Ah
Twenty tiri k
Miracle money
Ah ah ah ah ah
Ko le ye yin
But oma to ye yin
Omo iya aye